YOR Jérémie Chapitre 30

Jérémie 30

YOR · Comparer · Audio

1̀rọ̀ tí ó tọ Jeremiah wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá, wí pé: 2“Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Israẹli wí, pé: ‘Ìwọ kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ti bá ọ sọ sínú ìwé kan. 3Ọjọ́ ń bọ̀ nígbà tí ń ó mú àwọn ènìyàn mi, àwọn ọmọ Israẹli àti Juda kúrò nínú ìgbèkùn, tí n ó sì dá wọn padà sí orí ilẹ̀ tí mo fi fún àwọn baba ńlá wọn láti ní,’ ni Olúwa Ọlọ́run wí.” 4Ìwọ̀nyí ni àwọn ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run sí Israẹli àti Juda: 5“Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 6Béèrè kí o sì rí. 7Ọjọ́ náà yóò ha ti burú tó! 8“ ‘Ní ọjọ́ náà,’ Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí pé, 9Dípò bẹ́ẹ̀ wọn yóò máa sin Olúwa Ọlọ́run wọn 10“ ‘Nítorí náà, má ṣe bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu ìránṣẹ́ mi, Olúwa wí. 11Èmi wà pẹ̀lú rẹ, n ó sì gbà ọ́,’ Olúwa wí. 12“Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 13Kò sí ẹnìkan tí yóò bẹ̀bẹ̀ fún àìṣedéédéé yín, 14Gbogbo àwọn olùfẹ́ rẹ ti gbàgbé rẹ, 15Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń kígbe nítorí ọgbẹ́ yín, 16“ ‘Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ṣe yín ní ibi ni ibi yóò bá, 17Ṣùgbọ́n èmi yóò fi ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìlera fún yín, Olúwa wí, 18“Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 19Láti ẹnu wọn ni orin ọpẹ́ àti 20Ọmọ ọmọ wọn yóò wà bí i ti ìgbàanì 21Ọ̀kan nínú wọn ni yóò jẹ́ olórí wọn, Olúwa wí. 22‘Nítorí náà, ẹ̀yin yóò jẹ́ ènìyàn mi, 23Wò ó, ìbínú Olúwa yóò tú jáde, 24Ìbínú ńlá Olúwa kò ní dẹ̀yìn lẹ́yìn

Limite quotidienne atteinte

Mettez à jour votre plan pour continuer à utiliser les fonctionnalités de l'IA avec des limites quotidiennes plus élevées.

Comparer tous les forfaits →