YOR Jeremiah Kabanata 47

Jeremiah 47

YOR · Ihambing · Audio

1Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tó tọ wòlíì Jeremiah wá nípa àwọn Filistini, kí ó tó di pé Farao dojúkọ Gasa. 2Báyìí ni Olúwa wí: 3nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ìró títẹ̀lé pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin alágbára 4Nítorí tí ọjọ́ náà ti pé Olúwa ti ṣetán láti pa Filistini run, 5Gasa yóò fá irun orí rẹ̀ nínú ọ̀fọ̀. 6“Ẹ̀yin kígbe, ‘Yé è, idà Olúwa, 7Ṣùgbọ́n báwo ni yóò ṣe sinmi, Olúwa ti pàṣẹ fún un,

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →