YOR Isaiah Kabanata 23

Isaiah 23

YOR · Ihambing · Audio

1̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Tire. 2Dákẹ́ jẹ́ẹ́, ẹ̀yin ènìyàn erékùṣù 3Láti orí àwọn omi ńlá 4Kí ojú kí ó tì ọ́, ìwọ Sidoni àti ìwọ 5Nígbà tí ọ̀rọ̀ bá dé Ejibiti, 6Kọjá wá sí Tarṣiṣi; 7Ǹjẹ́ èyí náà ni ìlú àríyá yín, 8Ta ló gbèrò èyí sí Tire, 9Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti ṣètò rẹ̀, 10Tu ilẹ̀ rẹ gẹ́gẹ́ bí i ti ipadò odò Ejibiti, 11Olúwa ti na ọwọ́ rẹ̀ jáde sí orí Òkun 12Ó wí pé, “Kò sí àríyá fún ọ mọ́, 13Bojú wo ilẹ̀ àwọn ará Babeli, 14Hu, ìwọ ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi; 15Ní àkókò náà a ó gbàgbé Tire fún àádọ́rin ọdún, ọjọ́ ayé ọba kan. Ṣùgbọ́n ní òpin àádọ́rin ọdún wọ̀nyí, yóò ṣẹlẹ̀ sí Tire gẹ́gẹ́ bí orin àgbèrè: 16“Mú dùùrù kan, rìn kọjá láàrín ìlú, 17Ní òpin àádọ́rin ọdún náà, Olúwa yóò bá Tire jà. Òun yóò sì padà sí àyálò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí panṣágà, yóò sì máa ṣe òwò rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ ọba tí ó wà ní ilẹ̀ ayé. 18Síbẹ̀síbẹ̀ èrè rẹ̀ àti owó iṣẹ́ rẹ̀ ni a ó yà sọ́tọ̀ fún Olúwa; a kò ní kó wọn pamọ́ tàbí kí a há wọn mọ́wọ́. Ère rẹ̀ ni a ó fi fún àwọn tí ó ń gbé níwájú Olúwa, fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ àti aṣọ.

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →