YOR 2 Samuel Kabanata 22

2 Samuel 22

YOR · Ihambing · Audio

1Dafidi sì kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sí Olúwa ní ọjọ́ tí Olúwa gbà á kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ Saulu. 2Ó sì wí pé, Olúwa ni àpáta mi, àti Olùgbàlà mi; 3Ọlọ́run mi, àpáta mi, nínú ẹni tí èmi ní ààbò, 4“Èmi ké pe Olúwa, tí ó yẹ láti máa yìn, 5Nígbà tí ìbìlù ìrora ikú yí mi káàkiri; 6Ọ̀já isà òkú yí mi káàkiri; 7“Nínú ìpọ́njú mi, èmi ké pé Olúwa, 8Ilẹ̀ sì mì, ó sì wárìrì; 9Èéfín ti ihò imú rẹ̀ jáde wá, 10Ó tẹ orí ọ̀run ba pẹ̀lú, ó sì sọ̀kalẹ̀; 11Ó sì gun orí kérúbù, ó sì fò, 12Ó sì fi òkùnkùn ṣe ibùjókòó yí ara rẹ̀, àti àgbájọ omi, 13Nípasẹ̀ ìmọ́lẹ̀ iwájú rẹ̀ 14Olúwa sán àrá láti ọ̀run wá, 15Ó sì ta ọfà, ó sì tú wọn ká; 16Ìṣàn ibú òkun sì fi ara hàn, Olúwa, 17“Ó ránṣẹ́ láti òkè wá, ó mú mi; 18Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi alágbára, 19Wọ́n wá láti borí mi lọ́jọ́ ìpọ́njú mi, Olúwa ni aláfẹ̀yìntì mi. 20Ó sì mú mi wá sí ààyè ńlá, 21“Olúwa sán án fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi; 22Nítorí pé èmi pa ọ̀nà Olúwa mọ́, 23Nítorí pé gbogbo ìdájọ́ rẹ̀ ni ó wà níwájú mi; 24Èmi sì wà nínú ìwà títọ́ sí í, 25Olúwa sì san fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi, 26“Fún aláàánú ni ìwọ ó fi ara rẹ̀ hàn ni aláàánú, 27Fún onínú funfun ni ìwọ fi ara rẹ hàn ní funfun; 28Àwọn ènìyàn tí ó wà nínú ìyà ni ìwọ ó sì gbàlà; 29Nítorí ìwọ ni ìmọ́lẹ̀ mi, Olúwa; Olúwa yóò sì sọ òkùnkùn mi di ìmọ́lẹ̀. 30Bẹ́ẹ̀ ni nítorí nípa rẹ̀ ni èmi ti la àárín ogun kọjá; 31“Ọlọ́run yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀; Olúwa ni a ti dánwò. 32Nítorí ta ni Ọlọ́run, bí kò ṣe Olúwa? 33Ọlọ́run alágbára ni ó fún mi ní agbára, 34Ó ṣe ẹsẹ̀ mi bí ẹsẹ̀ abo àgbọ̀nrín; 35Ó kọ́ ọwọ́ mi ní ogun jíjà; 36Ìwọ sì ti fún mi ní asà ìgbàlà rẹ̀; 37Ìwọ sì sọ ìtẹ̀lẹ̀ di ńlá ní abẹ́ mi; 38“Èmi ti lépa àwọn ọ̀tá mi, èmi sì ti run wọ́n, 39Èmi ti pa wọ́n run, èmi sì ti fọ́ wọn, 40Ìwọ sì ti fi agbára dì mí ní àmùrè fún ìjà; 41Ìwọ sì mú àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà fún mi, 42Wọ́n wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan láti gbà wọ́n; Olúwa, ṣùgbọ́n kò dá àwọn lóhùn. 43Nígbà náà ni èmi sì gún wọn wẹ́wẹ́ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, 44“Ìwọ sì gbà mí kúrò lọ́wọ́ ìjà àwọn ènìyàn mi, 45Àwọn àjèjì wá láti tẹríba fún mi; 46Àyà yóò pá àwọn àlejò, 47“Olúwa ń bẹ́; olùbùkún sì ni àpáta mi! 48Ọlọ́run ni ẹni tí ń gbẹ̀san mi, 49Àti ẹni tí ó gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi. 50Nítorí náà èmi ó fi ọpẹ́ fún ọ, Olúwa, 51“Òun ni ilé ìṣọ́ ìgbàlà fún ọba rẹ̀;

Naabot na ang Pang-araw-araw na Limitasyon

I-upgrade ang iyong plan upang magpatuloy sa paggamit ng AI features na may mas mataas na daily limits.

Ikumpara ang lahat ng plano →