YOR Psalm Luku 55

Psalm 55

YOR · Vertaa · Audio

1Fi etí sí àdúrà mi, Ọlọ́run, 2gbọ́ mi kí o sì dá mi lóhùn. 3Sí ohùn àwọn ọ̀tá ni, 4Ọkàn mi wà nínú ìrora pẹ̀lú; 5Ìbẹ̀rù àti ìwárìrì wa sí ara mi; 6Èmi sọ pé, “Èmi ìbá ní ìyẹ́ bí àdàbà! 7Èmi ìbá sálọ, jìnnà réré, 8èmi ìbá yára lọ́ si ibùgbé mi ní ibi ààbò, 9Da àwọn ẹni búburú láàmú, Olúwa, da ahọ́n wọn rú, 10Ọ̀sán àti òru ni wọ́n fi ń rìn gbogbo odi kiri; 11Ìwà búburú ń bẹ ní àárín rẹ̀; 12Tí ọ̀tá bá tàbùkù mi, 13Ṣùgbọ́n tí ó bá ṣe ìwọ, ọkùnrin bí ẹgbẹ́ mi, 14pẹ̀lú ẹni tí èmi ti jẹ ìgbádùn adùn ìdàpọ̀, 15Kí ikú kí ó dé bá wọn, 16Ṣùgbọ́n èmi pe Ọlọ́run; Olúwa yóò sì gbà mí. 17Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sán 18Ó rà mí padà láìléwu 19Ọlọ́run yóò gbọ́, yóò sì pọ́n wọn lójú àní, Sela, 20Ọ̀rẹ́ mi yìí ti dalẹ̀ èmi ọ̀rẹ́ rẹ̀; 21Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ kúnná ju òrí-àmọ́, 22Gbé ẹrù rẹ lọ sí ọ̀dọ̀ Olúwa 23Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni yóò mu àwọn ọ̀tá mi

Päivittäinen raja saavutettu

Päivitä palvelupakettia jatkaaksesi AI-ominaisuuksien käyttöä korkeammilla päivittäisillä rajoilla.

Vertaa kaikkia tilauksia →