YOR Joel Luku 1

Joel 1

YOR · Vertaa · Audio

1̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Joẹli ọmọ Petueli wá. 2Ẹ gbọ́ èyí ẹ̀yin àgbàgbà; 3Ẹ sọ ọ́ fún àwọn ọmọ yín, 4Èyí tí eṣú tí agénijẹ jẹ kù 5Ẹ jí gbogbo ẹ̀yin ọ̀mùtí kí ẹ sì sọkún 6Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti ṣígun sí ilẹ̀ mìíràn 7Ó ti pa àjàrà mi run, 8Ẹ pohùnréré ẹkún bí wúńdíá 9A ké ọrẹ jíjẹ́ àti ọrẹ mímu Olúwa. Olúwa. 10Oko di ìgboro, ilẹ̀ ń ṣọ̀fọ̀, 11Kí ojú kí ó tì yín, ẹ̀yin àgbẹ̀; 12Àjàrà gbẹ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì rọ̀ dànù; 13Ẹ di ara yín ni àmùrè, 14Ẹ yà àwẹ̀ kan sí mímọ́, Olúwa Ọlọ́run yín, Olúwa. 15A! Fún ọjọ́ náà, Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀, 16A kò ha ké oúnjẹ kúrò níwájú 17Irúgbìn bàjẹ́ nínú ebè wọn, 18Àwọn ẹranko tí ń kérora tó! 19Olúwa, sí ọ ni èmi o ké pè, 20Àwọn ẹranko igbó gbé ojú sókè sí ọ pẹ̀lú,

Päivittäinen raja saavutettu

Päivitä palvelupakettia jatkaaksesi AI-ominaisuuksien käyttöä korkeammilla päivittäisillä rajoilla.

Vertaa kaikkia tilauksia →