YOR Job Luku 28

Job 28

YOR · Vertaa · Audio

1Nítòótọ́, koto fàdákà ń bẹ, 2Nínú ilẹ̀ ni à ń gbé ń wa irin, 3Ènìyàn ni ó fi òpin si òkùnkùn, 4Wọ́n wa ihò ilẹ̀ tí ó jì sí àwọn tí ń gbé òkè, 5Bí ó ṣe ti ilẹ̀ ni, nínú rẹ̀ ni oúnjẹ ti ń jáde wá, 6òkúta ibẹ̀ ni ibi òkúta safire, 7Ipa ọ̀nà náà ni ẹyẹ kò mọ̀, 8Àwọn ẹranko agbéraga kò rìn ibẹ̀ rí, 9Ó fi ọwọ́ rẹ̀ lé akọ òkúta, 10Ó sì la ipa odò ṣíṣàn nínú àpáta, 11Ó sì ṣe ìṣàn odò kí ó má ṣe kún àkúnya, 12Ṣùgbọ́n níbo ni á ó gbé wá ọgbọ́n rí, 13Ènìyàn kò mọ iye rẹ̀, 14Ọ̀gbun wí pé, “Kò sí nínú mi”; 15A kò le è fi wúrà rà á, 16A kò le è fi wúrà Ofiri, tàbí òkúta óníkìsì iyebíye, 17Wúrà àti òkúta kristali kò tó ẹgbẹ́ rẹ̀; 18A kò lè dárúkọ iyùn tàbí òkúta jasperi; 19Òkúta topasi ti Kuṣi kò tó ẹgbẹ́ rẹ̀; 20Níbo ha ni ọgbọ́n ti jáde wá? 21A rí i pé, ó fi ara sinko kúrò ní ojú àwọn alààyè gbogbo, 22Ibi ìparun àti ikú wí pé, 23Ọlọ́run ni ó mọ òye ipa ọ̀nà rẹ̀, 24Nítorí pé ó wòye dé òpin ayé, 25láti dà òsùwọ̀n fún afẹ́fẹ́, 26Nígbà tí ó pàṣẹ fún òjò, 27nígbà náà ni ó rí i, ó sì sọ ọ́ jáde; 28Àti fún ènìyàn ni ó wí pé,

Päivittäinen raja saavutettu

Päivitä palvelupakettia jatkaaksesi AI-ominaisuuksien käyttöä korkeammilla päivittäisillä rajoilla.

Vertaa kaikkia tilauksia →