YOR Isaiah Luku 44

Isaiah 44

YOR · Vertaa · Audio

1Ṣùgbọ́n gbọ́ nísinsin yìí, ìwọ Jakọbu ìránṣẹ́ mi, 2Ohun tí Olúwa wí nìyìí 3Nítorí èmi yóò da omi sí ilẹ̀ tí ń pòǹgbẹ 4Wọn yóò dàgbàsókè gẹ́gẹ́ bí i koríko nínú pápá oko tútù, 5Ọ̀kan yóò wí pé, ‘Èmi jẹ́ ti Olúwa’; Olúwa,’ Olúwa ni, kì í ṣe ère òrìṣà 6“Ohun tí Olúwa wí nìyìí Olúwa àwọn ọmọ-ogun. 7Ta ni ó dàbí ì mi? Jẹ́ kí o kéde rẹ̀. 8Má ṣe wárìrì, má ṣe bẹ̀rù. 9Gbogbo àwọn tí ń gbẹ́ ère jásí asán, 10Ta ni ó mọ òrìṣà kan tí ó sì ya ère, 11Òun àti nǹkan rẹ̀ wọ̀nyí ni a ó dójútì; 12Alágbẹ̀dẹ mú ohun èlò, 13Gbẹ́nàgbẹ́nà fi ìwọ̀n wọ́n ọ́n 14Ó gé igi kedari lulẹ̀, 15Ohun èlò ìdáná ni fún ènìyàn; 16Ìlàjì igi náà ni ó jó nínú iná; 17Nínú èyí tí ó kù ni ó ti ṣe òrìṣà, ère rẹ̀; 18Wọn kò mọ nǹkan kan, nǹkan kan kò yé wọn; 19Kò sí ẹni tí ó dúró láti ronú, 20Ó ń jẹ eérú, ọkàn ẹlẹ́tàn ni ó ṣì í lọ́nà; 21“Rántí àwọn nǹkan wọ̀nyí, ìwọ Jakọbu, 22Èmi ti gbá gbogbo ìkùnà rẹ dànù bí i kurukuru, 23Kọrin fáyọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, nítorí Olúwa ló ti ṣe èyí; Olúwa ti ra Jakọbu padà, 24“Ohun tí Olúwa wí nìyìí Olúwa 25ta ni ó ba àmì àwọn wòlíì èké jẹ́ 26ẹni tí ó gbé ọ̀rọ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ jáde 27ta ni ó sọ fún omi jíjìn pé, ‘Ìwọ gbẹ, 28ta ni ó sọ nípa Kirusi pé, ‘Òun ni Olùṣọ́-àgùntàn mi

Päivittäinen raja saavutettu

Päivitä palvelupakettia jatkaaksesi AI-ominaisuuksien käyttöä korkeammilla päivittäisillä rajoilla.

Vertaa kaikkia tilauksia →