YOR Ecclesiastes Luku 7

Ecclesiastes 7

YOR · Vertaa · Audio

1Orúkọ rere sàn ju ìpara olóòórùn dídùn lọ, 2Ó dára láti lọ sí ilé ọ̀fọ̀ 3Ìbànújẹ́ dára ju ẹ̀rín lọ, 4Ọkàn ọlọ́gbọ́n wà ní ilé ọ̀fọ̀, 5Ó dára láti gba ìbáwí ọlọ́gbọ́n, 6Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀gún ti ń dún lábẹ́ ìkòkò 7Ìrẹ́jẹ a máa sọ ọlọ́gbọ́n di òmùgọ̀, 8Òpin ọ̀rọ̀ dára ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ, 9Má ṣe yára bínú ní ọkàn rẹ 10Má ṣe sọ wí pé, “Kí ni ìdí tí àtijọ́ fi dára ju èyí?” 11Ọgbọ́n, gẹ́gẹ́ bí ogún ìní jẹ́ ohun tí ó dára 12Ọgbọ́n jẹ́ ààbò 13Wo ohun tí Ọlọ́run ti ṣe: 14Nígbà tí àkókò bá dára, jẹ́ kí inú rẹ dùn, 15Nínú ayé àìní ìtumọ̀ yìí ni mo ti rí gbogbo èyí 16Má ṣe jẹ́ olódodo jùlọ 17Ìwọ ma ṣe búburú jùlọ kí ìwọ má sì ṣe aṣiwèrè, 18Ó dára láti mú ọ̀kan 19Ọgbọ́n máa ń mú kí ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára 20Kò sí olódodo ènìyàn kan láyé 21Má ṣe kíyèsi gbogbo ọ̀rọ̀ tí ènìyàn ń sọ 22Tí o sì mọ̀ nínú ọkàn rẹ 23Gbogbo èyí ni mo ti dánwò nípa ọgbọ́n, tí mo sì wí pé, 24Ohun tí ó wù kí ọgbọ́n le è jẹ́, 25Mo wá rò ó nínú ọkàn mi láti mọ̀, 26Mo rí ohun tí ó korò ju ikú lọ 27Oniwaasu wí pé, “Wò ó, eléyìí ni ohun tí mo ti ṣàwárí: 28Nígbà tí mo sì ń wá a kiri 29Eléyìí nìkan ni mo tí ì rí:

Päivittäinen raja saavutettu

Päivitä palvelupakettia jatkaaksesi AI-ominaisuuksien käyttöä korkeammilla päivittäisillä rajoilla.

Vertaa kaikkia tilauksia →