Proverbios 29
1Ẹni tí ó sì ń ṣorí kunkun lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáwí 2Nígbà tí olódodo bá ń gbilẹ̀, àwọn ènìyàn a yọ̀ 3Ènìyàn tí ó fẹ́ràn ọgbọ́n mú kí baba rẹ̀ láyọ̀ 4Nípa ìdájọ́ òdodo ni ọba fi í mú ìlú tòrò nini, 5Ẹnikẹ́ni tí ó bá tan aládùúgbò rẹ̀ 6Ẹ̀ṣẹ̀ ènìyàn ibi ni ó jẹ́ ìdẹ̀kùn rẹ̀ 7Olódodo ń máa ro ọ̀rọ̀ tálákà, 8Àwọn ẹlẹ́yà a máa ru ìlú sókè, 9Bí ọlọ́gbọ́n ènìyàn bá lọ sí ilé ẹjọ́ pẹ̀lú aláìgbọ́n 10Àwọn tí ó ń tàjẹ̀ sílẹ̀ kò rí ẹni dídúró ṣinṣin 11Aláìgbọ́n ènìyàn fi gbogbo ẹnu rẹ̀ bínú 12Bí olórí bá fetí sí irọ́, 13Tálákà ènìyàn àti aninilára jọ ní àbùdá yìí, Olúwa jẹ́ kí ojú àwọn méjèèjì máa ríran. 14Bí ọba kan bá ń ṣe ìdájọ́ tálákà pẹ̀lú òtítọ́ 15Ọ̀pá ìbániwí ń fún ni ní ọgbọ́n 16Nígbà tí ènìyàn búburú ń gbilẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀ṣẹ̀ ń gbilẹ̀ 17Bá ọmọ rẹ wí, yóò sì fún ọ ní àlàáfíà 18Níbi tí kò ti sí ìfihàn, àwọn ènìyàn a gbé ìgbé ayé àìbìkítà, 19A kò le fi ọ̀rọ̀ lásán kìlọ̀ fún ìránṣẹ́ 20Ǹjẹ́ ó rí ènìyàn tí ń kánjú sọ̀rọ̀? 21Bí ènìyàn kan bá kẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ lákẹ̀ẹ́jù láti kékeré 22Oníbìínú ènìyàn a ru ìjà sókè, 23Ìgbéraga ènìyàn a máa sọ ọ́ di ẹni ilẹ̀ 24Ẹni tí ó ń kó ẹgbẹ́, olè kórìíra ọkàn ara rẹ̀, 25Ìbẹ̀rù ènìyàn kan yóò sì di ìdẹ̀kùn Olúwa wà láìléwu. 26Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ń wá ojúrere alákòóso, Olúwa ni ènìyàn tí ń gba ìdájọ́ òdodo. 27Olódodo kórìíra àwọn aláìṣòótọ́: