YOR Παροιμίες Κεφάλαιο 18

Παροιμίες 18

1Ènìyàn tí kò ba ni rẹ́ a máa lépa ìmọ̀ ara rẹ̀; 2Aláìgbọ́n kò rí inú dídùn sí òye 3Nígbà ti ènìyàn búburú dé ni ẹ̀gàn dé, 4Ọ̀rọ̀ ẹnu ènìyàn jẹ́ omi jíjìn, 5Kò dára kí ènìyàn ṣe ojúsàájú fún ènìyàn búburú 6Ètè aláìgbọ́n dá ìjà sílẹ̀ 7Ẹnu aláìgbọ́n ni ó ba tirẹ̀ jẹ́, 8Ọ̀rọ̀ olófòófó dàbí oúnjẹ àdídùn; 9Ẹni tí kò ṣe déédé nínú iṣẹ́ rẹ̀ 10Orúkọ Olúwa, ilé ìṣọ́ agbára ni; 11Ọ̀rọ̀ olówó ni ìlú olódi wọn; 12Ṣáájú ìṣubú ọkàn ènìyàn a kọ́kọ́ máa gbéraga, 13Ẹni tí ó ń fèsì kí ó tó gbọ́, 14Ọkàn ènìyàn a máa gbé e ró nígbà àìsàn, 15Ọkàn olóye ní i gba ìmọ̀; 16Ẹ̀bùn máa ń ṣí ọ̀nà fún ẹni tí ń fún ni lẹ́bùn 17Ẹni tí ó kọ́kọ́ rọjọ́ máa ń dàbí i pé ó jàre, 18Ìbò dídì máa ń parí ìjà 19Arákùnrin tí a ṣẹ̀ sí ṣòro yípadà ju ìlú olódi lọ, 20Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ikùn ènìyàn a yó; 21Ikú àti ìyè ń bẹ nípa ahọ́n wọn, 22Ẹni tí ó rí aya fẹ́, rí ohun rere, Olúwa. 23Tálákà ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú, 24Ènìyàn tí ó ní ọ̀rẹ́ púpọ̀ le è parun,

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →