Jesaja 5
1Èmi yóò kọrin fún ẹni tí mo fẹ́ràn 2Ó tu ilẹ̀ rẹ̀, ó ṣa òkúta ibẹ̀ kúrò 3“Ní ìsinsin yìí ẹ̀yin olùgbé Jerusalẹmu 4Kín ni ó kù tí n ò bá túnṣe sí ọgbà àjàrà mi. 5Ní ìsinsin yìí, èmi yóò wí fún ọ 6Èmi yóò sì sọ ọ́ di ahoro 7Ọgbà àjàrà Olúwa àwọn ọmọ-ogun 8Ègbé ni fún àwọn tí ń kọ́lé mọ́lé 9Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti sọ ọ́ sí mi létí: 10Ọgbà àjàrà sáré oko mẹ́wàá yóò mú 11Ègbé ni fún àwọn tí wọ́n dìde 12Wọ́n ní dùùrù àti ohun èlò orin olókùn níbi àsè wọn, Olúwa sí, 13Nítorí náà àwọn ènìyàn mi yóò lọ sí ìgbèkùn 14Nítorí náà isà òkú ti ń dátọ́mì gidigidi, 15Báyìí, ènìyàn yóò di ìrẹ̀sílẹ̀ 16Ṣùgbọ́n Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni a ó gbéga nípa ẹ̀tọ́ rẹ̀, 17Nígbà náà ni àwọn àgùntàn yóò máa jẹ́ ko ní ibùgbé e wọn, 18Ègbé ni fún àwọn tí ń fi ohun asán fa ẹ̀ṣẹ̀, 19sí àwọn tí ó sọ pé, “Jẹ́ kí Ọlọ́run ṣe kíákíá, 20Ègbé ni fún àwọn tí ń pe ibi ní rere, àti rere ní ibi, 21Ègbé ni fún àwọn tí ó gbọ́n lójú ara wọn 22Ègbé ni fún àwọn akọni nínú wáìnì mímu 23tí wọ́n dá ẹlẹ́bi sílẹ̀ nítorí àbẹ̀tẹ́lẹ̀, 24Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí ahọ́n iná ṣe ń jó àgékù koríko run Olúwa àwọn ọmọ-ogun sílẹ̀ 25Nítorí náà, ìbínú Olúwa gbóná si àwọn ènìyàn rẹ̀, 26Yóò sì gbé ọ̀págun sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ó jìnnà, 27Kò sí ẹni tí yóò rẹ̀ nínú wọn, tàbí tí yóò kọsẹ̀, 28Àwọn ọfà wọn múná, 29Bíbú wọn dàbí tí kìnnìún, 30Ní ọjọ́ náà, wọn yóò hó lé e lórí