YOR 1. Chronik Kapitel 3

1. Chronik 3

YOR · Vergleichen · Audio

1Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Hebroni. 2ẹ̀kẹta sì ni Absalomu ọmọ Maaka ọmọbìnrin Talmai ọba Geṣuri bí fún un; 3ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ Abitali; 4Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà. 5Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu: 6Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7Noga, Nefegi, Jafia, 8Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n. 9Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn. 10Ọmọ Solomoni ni Rehoboamu, 11Jehoramu ọmọ rẹ̀, 12Amasiah ọmọ rẹ̀, 13Ahasi ọmọ rẹ̀, 14Amoni ọmọ rẹ̀, 15Àwọn ọmọ Josiah: 16Àwọn ìran ọmọ Jehoiakimu: 17Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn: 18Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah. 19Àwọn ọmọ Pedaiah: 20Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi. 21Àwọn ọmọ Hananiah: 22Àwọn ọmọ Ṣekaniah: 23Àwọn ọmọ Neariah: 24Àwọn ọmọ Elioenai:

Tägliches Limit erreicht

Aktualisieren Sie Ihren Plan, um KI-Funktionen mit höheren täglichen Limits weiter nutzen zu können.

Alle Tarife vergleichen →