YOR Proverbs Kapitel 13

Proverbs 13

YOR · Sammenlign · Lyd

1lọ́gbọ́n ọmọ gba ẹ̀kọ́ baba rẹ̀, 2Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ènìyàn ń gbádùn ohun rere, 3Ẹnikẹ́ni tí ó ṣọ́ ẹnu rẹ̀ pa ẹnu ara rẹ̀ mọ́, 4Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkan kan, 5Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́, 6Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú, 7Ènìyàn kan díbọ́n bí ẹni tí ó ní ọrọ̀ síbẹ̀ kò ní nǹkan kan 8Ọrọ̀ ènìyàn le è ra ẹ̀mí rẹ̀ 9Ìmọ́lẹ̀ olódodo tàn roro, 10Ìgbéraga máa ń dá ìjà sílẹ̀ ni 11Owó tí a fi ọ̀nà èrú kójọ yóò ṣí lọ, 12Ìrètí tí ń falẹ̀ máa ń mú kí ọkàn ṣàárẹ̀ 13Ẹni tí ó kẹ́gàn ẹ̀kọ́ yóò jìyà rẹ̀ 14Ìkọ́ni ọlọ́gbọ́n jẹ́ orísun ìyè, 15Òye pípé ń mú ni rí ojúrere, 16Gbogbo olóye ènìyàn máa ń hùwà pẹ̀lú ìmọ̀, 17Ìránṣẹ́ búburú bọ́ sínú ìdààmú 18Ẹni tí ó kọ ìbáwí yóò di tálákà yóò sì rí ìtìjú, 19Ìfẹ́ tí a mú ṣẹ dùn mọ́ ọkàn 20Ẹni tí ó ń bá ọlọ́gbọ́n rìn yóò gbọ́n 21Òsì a máa ta ẹlẹ́ṣẹ̀, 22Ènìyàn rere a máa fi ogún sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀, 23Ilẹ̀ ẹ tálákà le è mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìre oko wá 24Ẹni tí ó fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀ 25Olódodo jẹ́wọ́ títí ó fi tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →