YOR Job Kapitel 5

Job 5

YOR · Sammenlign · Lyd

1Ó jẹ́ pé nísinsin yìí bí ẹnìkan bá wà tí yóò dá wa lóhùn? 2Nítorí pé ìbínú pa aláìmòye, 3Èmi ti rí aláìmòye ti ó ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n lulẹ̀, 4Àwọn ọmọ rẹ̀ kò jìnnà sí ewu, 5Ìkórè oko ẹni tí àwọn tí ebi ń pa sọ̀ di jíjẹ, 6Bí ìpọ́njú kò bá ti inú erùpẹ̀ jáde wá ni, 7Ṣùgbọ́n a bí ènìyàn sínú wàhálà, 8“Ṣùgbọ́n bí ó ṣe tèmi, ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ní èmi yóò ti ṣìpẹ̀, 9Ẹni tí ó ṣe ohun tí ó tóbi tí a kò lè ṣe àwárí, 10Tí ń rọ̀jò sí orí ilẹ̀ ayé 11Láti gbé àwọn orílẹ̀-èdè lékè 12Ó yí ìmọ̀ àwọn alárékérekè po, 13Ó mú àwọn ọlọ́gbọ́n nínú àrékérekè ara wọn, 14Wọ́n sáré wọ inú òkùnkùn ní ọ̀sán; 15Ṣùgbọ́n ó gba tálákà là ní ọwọ́ idà, 16Bẹ́ẹ̀ ni ìrètí wà fún tálákà, 17“Kíyèsi i, ìbùkún ni fún ẹni tí Ọlọ́run bá wí, 18Nítorí pé òun a máa pa ni lára, síbẹ̀ òun a sì tún dì í ní ìdì ìtura, 19Yóò gbà ọ́ nínú ìpọ́njú mẹ́fà, 20Nínú ìyanu yóò gbà ọ́ lọ́wọ́ ikú 21A ó pa ọ́ mọ́ kúrò lọ́wọ́ iná ahọ́n, 22Ìwọ yóò rẹ́rìn-ín nínú ìparun àti ìyàn, 23Nítorí pé ìwọ ti bá òkúta igbó mulẹ̀, 24Ìwọ ó sì mọ̀ pé àlàáfíà ni ibùjókòó rẹ wà, 25Ìwọ ó sì mọ̀ pẹ̀lú pé irú-ọmọ rẹ ó sì pọ̀ 26Ìwọ yóò wọ isà òkú rẹ ní ògbólógbòó ọjọ́, 27“Kíyèsi i, àwa ti wádìí rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ní ó rí!

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →