YOR Psalm Kapitola 50

Psalm 50

YOR · Porovnat · Audio

1Olúwa, Ọlọ́run alágbára, 2Láti Sioni wá, pípé ni ẹwà, 3Ọlọ́run ń bọ̀, 4Yóò sì pe àwọn ọ̀run láti òkè wá jọ àti ayé, 5“Kó àwọn ènìyàn mímọ́ jọ fún mi 6Àwọn ọ̀run yóò sì sọ̀rọ̀ òdodo rẹ̀, 7“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ènìyàn mi, èmi yóò si sọ̀rọ̀, ìwọ Israẹli, èmi yóò jẹ́rìí sí ọ: 8Èmi kí yóò bá ọ wí 9Èmí kò fẹ́ kí ó mú akọ màlúù láti inú ilé tí o kọ́ fún un, 10nítorí gbogbo ẹran igbó ni tèmi 11Èmi mọ gbogbo ẹyẹ ní orí àwọn òkè ńlá 12Bí ebi tilẹ̀ ń pa mí, èmi kì yóò sọ fún ọ, 13Ǹjẹ́ èmi yóò ha jẹ ẹran akọ màlúù tàbí 14“Rú ẹbọ ọpẹ́ sí Ọlọ́run, 15Kí o sì pè mí ní ọjọ́ ìpọ́njú, 16Ṣùgbọ́n Ọlọ́run sọ fún àwọn, ènìyàn búburú: 17Ìwọ kórìíra àṣẹ mi, 18Nígbà tí ìwọ rí olè, ìwọ dára pọ̀ mọ́ ọn, 19Ìwọ lo ẹnu rẹ fún aburú, 20Ní ìgbà gbogbo ìwọ ń sọ̀rọ̀ sí arákùnrin rẹ, 21Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ ti ṣe, mo sì dákẹ́; 22“Ǹjẹ́ ìwọ ro èyí wò, ẹ̀yin tí ó gbàgbé Ọlọ́run. 23Ẹni tí ó ba ní ẹbọ ọrẹ-ọpẹ́ bu ọlá fún mi; kí ó sì tún ọ̀nà rẹ̀ ṣe,

Dosažen denní limit

Upgraďte svůj plán a pokračujte v používání funkcí AI s vyššími denními limity.

Porovnat všechny plány →