Judges 5
1Nígbà náà ni Debora àti Baraki ọmọ Abinoamu kọ orin ní ọjọ́ náà wí pé, 2“Nítorí bí àwọn olórí ti síwájú ní Israẹli, Olúwa! 3“Ẹ gbọ́ ẹ̀yin ọba! Ẹ fetí yín sílẹ̀ ẹ̀yin ọmọ-aládé! Olúwa, Olúwa: Ọlọ́run Israẹli. 4“Olúwa nígbà tí o jáde kúrò ní Seiri, 5Àwọn òkè ńlá wárìrì ní iwájú Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni Sinai ní iwájú Olúwa 6“Ní ọjọ́ Ṣamgari ọmọ Anati, 7Àwọn olórí tán ní Israẹli, 8Wọ́n ti yan ọlọ́run tuntun, 9Àyà mi fà sí àwọn aláṣẹ Israẹli Olúwa! 10“Ẹ kéde rẹ̀: ẹ̀yin tí ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ funfun, 11ariwo àwọn tafàtafà, ní ibi tí a gbé ń fa omi. Olúwa, Olúwa 12‘Jí, jí, Debora! 13“Nígbà náà ni àwọn tókù sọ̀kalẹ̀ àwọn ọlọ́lá lọ; Olúwa tọ̀ mí wá pẹ̀lú àwọn alágbára. 14Àwọn kan jáde wá láti Efraimu, àwọn tí gbòǹgbò wọn wà ní Amaleki; 15Àwọn ọmọ-aládé Isakari wá pẹ̀lú Debora; 16Èéṣe tí ìwọ fi dúró pẹ́ láàrín agbo àgùntàn 17Gileadi dúró ní òkè odò Jordani. 18Àwọn ènìyàn Sebuluni fi ẹ̀mí wọn wéwu ikú; 19“Àwọn ọba wá, wọ́n sì jà; 20Àwọn ìràwọ̀ já láti ojú ọ̀run wá 21Odò Kiṣoni gbá wọn lọ, 22Nígbà náà ni pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin ki ilẹ̀, 23‘Ẹ fi Merosi bú,’ ni angẹli Olúwa wí. Olúwa, 24“Ìbùkún ni fún Jaeli, 25Ó béèrè omi, ó fún un ní wàrà; 26Ó na ọwọ́ rẹ̀ mú ìṣó àgọ́, 27Ní ẹsẹ̀ rẹ̀ ó wólẹ̀, 28“Ìyá Sisera yọjú láti ojú fèrèsé, 29Àwọn amòye obìnrin rẹ̀ dá a lóhùn; 30‘Wọn kò ha ń wa kiri, wọn kò ha ti pín ìkógun bi: 31“Bẹ́ẹ̀ ni kí ó jẹ́ kí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kí ó ṣègbé Olúwa!