YOR Isaiah Kapitola 45

Isaiah 45

YOR · Porovnat · Audio

1Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún ẹni òróró rẹ̀, 2Èmi yóò lọ síwájú rẹ, 3Èmi yóò sì fún ọ ní àwọn ọrọ̀ ibi òkùnkùn, Olúwa, 4Nítorí Jakọbu ìránṣẹ́ mi 5Èmi ni Olúwa, àti pé kò sí ẹlòmíràn; 6tí o fi jẹ́ pé láti ìlà-oòrùn Olúwa, lẹ́yìn mi kò sí ẹlòmíràn mọ́. 7Mo dá ìmọ́lẹ̀, mo sì dá òkùnkùn, Olúwa ni ó ṣe nǹkan wọ̀nyí. 8“Ìwọ ọ̀run lókè rọ òjò òdodo sílẹ̀; Olúwa ni ó ti dá a. 9“Ègbé ni fún ènìyàn tí ó ń bá Ẹlẹ́dàá rẹ̀ jà, 10Ègbé ni fún ẹni tí ó sọ fún baba rẹ̀ pé, 11“Ohun tí Olúwa wí nìyìí, 12Èmi ni ẹni tí ó dá ilẹ̀ ayé 13Èmi yóò gbé Kirusi sókè nínú òdodo mi. Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.” 14Ohun tí Olúwa wí nìyìí: 15Nítòótọ́ ìwọ jẹ́ Ọlọ́run tí ó fi ara rẹ̀ pamọ́, 16Gbogbo àwọn tí ó ń gbẹ́ ère ni ojú yóò tì 17Ṣùgbọ́n Israẹli ni a ó gbàlà láti ọwọ́ Olúwa 18Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí, Olúwa, 19Èmi kò sọ̀rọ̀ níbi tí ó fi ara sin, Olúwa sọ òtítọ́, 20“Ẹ kó ara yín jọ kí ẹ sì wá; 21Jẹ́ kí a mọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀, fihàn wá, Olúwa? 22“Yípadà sí mi kí a sì gbà ọ́ là, 23Nípa èmi tìkára mi ni mo ti búra, 24Wọn yóò sọ ní ti èmi, ‘Nínú Olúwa nìkan ni 25Ṣùgbọ́n nínú Olúwa gbogbo àwọn ìran Israẹli

Dosažen denní limit

Upgraďte svůj plán a pokračujte v používání funkcí AI s vyššími denními limity.

Porovnat všechny plány →