YOR 1 Chronicles Kapitola 8

1 Chronicles 8

YOR · Porovnat · Audio

1Benjamini jẹ́ baba: 2Noha ẹ̀ẹ̀kẹrin àti Rafa ẹ̀karùnún. 3Àwọn ọmọ Bela ni, 4Abiṣua, Naamani, Ahoa, 5Gera, Ṣefufani àti Huramu. 6Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati: 7Naamani Ahijah àti Gera, tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba Ussa àti Ahihudu. 8A bí àwọn ọmọkùnrin fún Ṣaharaimu ní Moabu lẹ́yìn tí ó ti kọ àwọn ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, Huṣimu àti Baara. 9Nípasẹ̀ ìyàwó rẹ̀ Hodeṣi ó ní Jobabu Sibia, Meṣa, Malkamu, 10Jeusi, Sakia àti Mirma. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé. 11Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali. 12Àwọn ọmọ Elipali: 13Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò. 14Ahio, Ṣasaki, Jeremoti, 15Sebadiah, Aradi, Ederi 16Mikaeli, Iṣifa àti Joha jẹ́ àwọn ọmọ Beriah. 17Sebadiah, Meṣullamu, Hiski, Heberi 18Iṣimerai, Isiliahi àti Jobabu jẹ́ àwọn ọmọ Elipali. 19Jakimu, Sikri, Sabdi, 20Elienai, Siletai, Elieli, 21Adaiah, Beraiah àti Ṣimrati jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣimei. 22Iṣipani Eberi, Elieli, 23Abdoni, Sikri, Hanani, 24Hananiah, Elamu, Anitotijah, 25Ifediah àti Penueli jẹ́ àwọn ọmọ Ṣasaki. 26Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah 27Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu. 28Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu. 29Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni. 30àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ Abdoni wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu, 31Gedori Ahio, Sekeri 32pẹ̀lú Mikiloti, tí ó jẹ́ baba Ṣimea. Wọ́n ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu. 33Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba Saulu àti Saulu baba Jonatani, Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali. 34Ọmọ Jonatani: 35Àwọn ọmọ Mika: 36Ahasi jẹ́ baba a Jeheada, Jeheada jẹ́ baba a Alemeti, Asmafeti àti Simri, Simri sì jẹ́ baba Mosa. 37Mosa jẹ́ baba Binea; Rafa sì jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀. 38Aseli ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: 39Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Eseki: 40Àwọn ọmọ Ulamu jẹ́ ògboyà jagunjagun tí ó lè gbá orin mú. Wọ́n ní ọ̀pọ̀ ọmọkùnrin àti ọmọ ọmọkùnrin áàdọ́jọ ní gbogbo rẹ̀.

Dosažen denní limit

Upgraďte svůj plán a pokračujte v používání funkcí AI s vyššími denními limity.

Porovnat všechny plány →