YOR Job অধ্যায় 17

Job 17

1Ẹ̀mí mi bàjẹ́, 2Nítòótọ́ àwọn ẹlẹ́yà wà lọ́dọ̀ mi, 3“Fi fún mi Olúwa, ìlérí tí ìwọ fẹ́; 4Nítorí pé ìwọ ti sé wọ́n láyà kúrò nínú òye; 5Ẹni tí ó sọ ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn dídún fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ fún èrè, 6“Ọlọ́run ti sọ mi di ẹni òwe fún àwọn ènìyàn; 7Ojú mí ṣú bàìbàì nítorí ìbìnújẹ́, 8Àwọn olódodo yóò yanu sí èyí, 9Olódodo pẹ̀lú yóò di ọ̀nà rẹ̀ mú, 10“Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti gbogbo yín, 11Ọjọ́ tí èmi ti kọjá, ìrò mi ti fà yá, 12Àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń ṣọ́ òru di ọ̀sán; 13Bí mo tilẹ̀ ní ìrètí, ipò òku ní ilé mi; 14Èmi ti wí fún ìdíbàjẹ́ pé, ìwọ ni baba mi, 15ìrètí mi ha dà nísinsin yìí? 16Yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sínú ipò òkú,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →