YOR Job অধ্যায় 20

Job 20

1Ìgbà náà ní Sofari, ará Naama dáhùn, ó sì wí pé, 2“Nítorí náà ní ìrò inú mi dá mi lóhùn, 3Mo ti gbọ́ ẹ̀san ẹ̀gàn mi, 4“Ìwọ kò mọ̀ èyí rí ní ìgbà àtijọ́, 5pé, orin ayọ̀ ènìyàn búburú, ìgbà kúkúrú ni, 6Bí ọláńlá rẹ̀ tilẹ̀ gòkè dé ọ̀run, 7ṣùgbọ́n yóò ṣègbé láéláé bí ìgbẹ́ ara rẹ̀; 8Yóò fò lọ bí àlá, a kì yóò sì rí i, 9Ojú tí ó ti rí i rí kì yóò sì rí i mọ́, 10Àwọn ọmọ rẹ̀ yóò máa wá àti rí ojúrere lọ́dọ̀ tálákà, 11Egungun rẹ̀ kún fún agbára ìgbà èwe rẹ̀, 12“Bí ìwà búburú tilẹ̀ dún ní ẹnu rẹ̀, 13bí ó tilẹ̀ dá a sì, tí kò si kọ̀ ọ́ sílẹ̀, 14ṣùgbọ́n oúnjẹ rẹ̀ nínú ikùn rẹ̀ ti yípadà, 15Ó ti gbé ọrọ̀ mì, yóò sì tún bí i jáde; 16Ó ti fà oró paramọ́lẹ̀ mú; 17Kì yóò rí odò wọ̀n-ọn-nì, 18Ohun tí ó ṣiṣẹ́ fún ni yóò mú un padà, kí yóò sì gbé e mì; 19Nítorí tí ó fi owó rẹ̀ ni tálákà lára, ó sì ti pẹ̀yìndà si wọ́n; 20“Nítorí òun kò mọ̀ ìwà pẹ̀lẹ́ nínú ara rẹ̀, 21Ohun kan kò kù fún jíjẹ́ rẹ̀; 22Nínú ànító rẹ̀, ìdààmú yóò dé bá a; 23Yóò sì ṣe, nígbà tí ó bá fẹ́ jẹun, 24Bi o tilẹ̀ sá kúrò lọ́wọ́ ohun ìjà ìrìn; 25O fà á yọ, ó sì jáde kúrò lára; 26òkùnkùn biribiri ní a ti pamọ́ fún ìṣúra rẹ̀. 27Ọ̀run yóò fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ hàn, 28Ìbísí ilé rẹ̀ yóò kọjá lọ, 29Èyí ni ìpín ènìyàn búburú láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →