YOR Song of Solomon অধ্যায় 4

Song of Solomon 4

1Báwo ni ìwọ ti lẹ́wà tó olólùfẹ́ mi! 2Eyín rẹ̀ funfun bí i irun àgbò 3Ètè rẹ dàbí òwú òdòdó; 4Ọrùn rẹ dàbí ilé ìṣọ́ Dafidi, 5Ọmú rẹ̀ méjèèjì dàbí abo egbin méjì 6Títí ọjọ́ yóò fi rọ̀ 7Gbogbo ara rẹ jẹ́ kìkì ẹwà, olólùfẹ́ mi; 8Kí a lọ kúrò ní Lebanoni, ìyàwó mi, 9Ìwọ ti gba ọkàn mi, arábìnrin mi, ìyàwó mi; 10Ìfẹ́ rẹ ti dùn tó, arábìnrin mi, ìyàwó mi! 11Ètè rẹ ń kan dídùn bí afárá oyin, ìyàwó mi; 12Arábìnrin mi ni ọgbà tí a sọ, arábìnrin mi, ìyàwó mi; 13Ohun ọ̀gbìn rẹ àgbàlá pomegiranate ni 14nadi àti Safironi, 15Ìwọ ni ọgbà orísun, kànga omi ìyè, 16Jí ìwọ afẹ́fẹ́ àríwá

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →