Amos 6
1Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ará rọ̀ ní Sioni 2Ẹ lọ Kalne kí ẹ lọ wò ó 3Ẹ̀yin sún ọjọ́ ibi síwájú, 4Ẹ̀yin sùn lé ibùsùn tí a fi eyín erin ṣe 5Ẹ̀yin ń lo ohun èlò orin bí i Dafidi 6Ẹ̀yin mu wáìnì ẹ̀kún ọpọ́n kan 7Nítorí náà, àwọn ni yóò lọ sí ìgbèkùn Olúwa Kórìíra Ìgbéraga Ọmọ Israẹli 8Olúwa Olódùmarè ti búra fúnra rẹ̀, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun sì ti wí pé: 9Bí ọkùnrin mẹ́wàá bá ṣẹ́kù nínú ilé kan, àwọn náà yóò kú. 10Bí ẹbí tí ó yẹ kí ó gbé òkú wọn jáde fún sínsin bá wọlé, bí o ba sì béèrè pé ǹjẹ́ ẹnìkan wa tí ó fi ara pamọ́ níbẹ̀, “Ǹjẹ́ ẹnìkankan wà lọ́dọ̀ yín?” tí ó bá sì dáhùn wí pé, “Rárá,” nígbà náà ni yóò wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́ àwa kò gbọdọ̀ dárúkọ Olúwa.” 11Nítorí Olúwa tí pa àṣẹ náà, 12Ǹjẹ́ ẹṣin a máa sáré lórí àpáta bí? 13Ẹ̀yin yọ̀ torí ìṣẹ́gun lórí Lo-Debari, 14Nítorí Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun wí pé,