Eyüp 35
1Elihu sì wí pe: 2“Ìwọ rò pé èyí ha tọ́, tí ìwọ wí pé, 3Nítorí tí ìwọ wí pé èrè kí ní yóò jásí fún ọ, 4“Èmi ó dá ọ lóhùn 5Síjú wo ọ̀run; kí o rí i, kí ó sì 6Bí ìwọ bá dẹ́ṣẹ̀, kí ni ìwọ fi sẹ̀ sí? 7Bí ìwọ bá sì ṣe olódodo, kí ni ìwọ fi fún un, 8Ìwà búburú rẹ ni fún ènìyàn bí ìwọ; 9“Nípa ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìninilára, wọ́n mú ni kígbe; 10Ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó wí pé, 11tí òun kọ́ wa ní ẹ̀kọ́ jù àwọn ẹranko ayé lọ, 12Nígbà náà ni wọ́n ń ké ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò dáhùn 13Nítòótọ́ Ọlọ́run kì yóò gbọ́ ọ̀rọ̀ asán; 14Bí ó tilẹ̀ ṣe pé ìwọ wí pé ìwọ kì í rí i, 15Ṣùgbọ́n nísinsin yìí nítorí tí ìbínú rẹ̀ kò tí fìyà jẹ ni, 16Nítorí náà ní Jobu ṣe ya ẹnu rẹ̀