YOR Yeremya Bölüm 2

Yeremya 2

YOR · Karşılaştır · Ses

1̀rọ̀ Olúwa sì tọ̀ mí wá wí pé: 2“Lọ kí o sì kéde sí etí Jerusalẹmu pé: Olúwa wí, 3Israẹli jẹ́ mímọ́ sí Olúwa, Olúwa wí. 4Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, ẹ̀yin ìdílé Jakọbu 5Báyìí ni Olúwa wí: 6Wọn kò béèrè, ‘Níbo ni Olúwa wà, 7Èmi mú yín wá sí ilẹ̀ ọlọ́ràá 8Àwọn àlùfáà kò béèrè wí pé, Olúwa wà?’ 9“Nítorí náà, mo fi ẹ̀sùn kàn yín lẹ́ẹ̀kan sí i,” Olúwa wí. 10Rékọjá lọ sí erékùṣù àwọn ara Kittimu, kí ẹ sì wò ó, 11Orílẹ̀-èdè kan ha á pa ọlọ́run rẹ̀ dà? 12Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́ṣẹ̀ méjì Olúwa wí. 13“Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́ṣẹ̀ méjì, 14Israẹli ha á jẹ́ ọmọ ọ̀dọ̀ ẹrú nípa ìbí? 15Àwọn kìnnìún ké ramúramù; 16Bákan náà, àwọn ọkùnrin Memfisi àti Tafanesi 17Ẹ̀yin kò ha a ti fa èyí sórí ara yín Olúwa Ọlọ́run sílẹ̀ 18Kí ló dé tí o ṣe wá lọ Ejibiti 19Iṣẹ́ búburú yín yóò fìyà jẹ yín Olúwa Ọlọ́run sílẹ̀, Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. 20“Nígbà àtijọ́, o ti fọ́ àjàgà rẹ sọnù, 21Èmi ti gbìn ọ́ gẹ́gẹ́ bí àjàrà ọ̀tọ̀, 22Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o wẹ ara rẹ pẹ̀lú sódà Olúwa Olódùmarè wí. 23“Báwo ni ìwọ ṣe wí pé, ‘Èmi kò ṣe aláìmọ́, 24Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó tí ń gbé aginjù 25Dá ẹsẹ̀ dúró láìwọ bàtà, 26“Gẹ́gẹ́ bí a ṣe ń dójútì olè nígbà tí a bá mú u, 27Wọ́n sọ fún igi pé, ‘Ìwọ ni baba mi,’ 28Níbo wá ni àwọn ọlọ́run tí ẹ ṣe fúnra yín ha a wà? 29“Kí ló dé tí o ṣe wá ń fi ẹ̀sùn kàn mí? Olúwa wí. 30“Nínú asán mo fìyà jẹ àwọn ènìyàn yín, 31“Ẹ̀yin ìran yìí, ẹ kíyèsi ọ̀rọ̀ Olúwa: 32Wúńdíá ha le gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀, 33Ìwọ ti jẹ́ ọlọ́gbọ́n tó nípa ọ̀rọ̀ ìfẹ́! 34Lórí aṣọ rẹ ni wọ́n bá 35ìwọ sọ wí pé, ‘Èmi jẹ́ aláìṣẹ̀; 36Èéṣe tí ìwọ fi ń lọ káàkiri 37Ìwọ yóò sì fi ibẹ̀ sílẹ̀ Olúwa ti kọ̀ àwọn tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé sílẹ̀,

Günlük Limit Ulaşıldı

Yapay Zeka özelliklerini daha yüksek günlük limitlerle kullanmaya devam etmek için planınızı yükseltin.

Tüm planları karşılaştır →