โยบ 40
1Olúwa dá Jobu lóhùn sí pẹ̀lú, ó sì wí pé, 2“Ẹni tí ń bá Olódùmarè wíjọ́ yóò ha kọ ní ẹ̀kọ́? 3Nígbà náà ni Jobu dá Olúwa lóhùn wá ó sì wí pé, 4“Kíyèsi i, ẹ̀gbin ni èmi—ohun kí ni èmi ó dà? 5Ẹ̀ẹ̀kan ní mo sọ̀rọ̀, ṣùgbọ́n èmi kì yóò tún sọ mọ́; 6Nígbà náà ní Olúwa dá Jobu lóhùn láti inú ìjì àyíká wá, ó sì wí pé, 7“Di àmùrè gírí ní ẹgbẹ́ rẹ bí ọkùnrin, 8“Ìwọ ha fẹ́ mú ìdájọ́ mi di asán? 9Ìwọ ni apá bí Ọlọ́run 10Fi ọláńlá àti ọlá ìtayọ rẹ̀ ṣe ara rẹ ní ọ̀ṣọ́, 11Mú ìrunú ìbínú rẹ jáde; 12Wo gbogbo ìwà ìgbéraga, ènìyàn kí o sì rẹ ẹ sílẹ̀ 13Sin gbogbo wọn papọ̀ nínú erùpẹ̀, 14Nígbà náà ní èmi ó yìn ọ́ pé, 15“Ǹjẹ́ nísinsin yìí kíyèsi Behemoti, 16Wò o nísinsin yìí, agbára rẹ wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ, 17Òun a máa jù ìrù rẹ̀ bí i igi kedari, 18Egungun rẹ̀ ní ògùṣọ̀ idẹ, 19Òun ni olórí nínú àwọn iṣẹ́ Ọlọ́run; 20Nítòótọ́ òkè ńlá ńlá ní i mu ohun jíjẹ fún un wá, 21Ó dùbúlẹ̀ lábẹ́ igi lótusì, 22Igi lótusì síji wọn bò o; 23Kíyèsi i, odò ńlá sàn jọjọ, òun kò sálọ; 24Ẹnìkan ha lè mú un ní ojú rẹ̀,