YOR Job Capitolul 7

Job 7

YOR · Comparați · Audio

1Ṣé ìjà kò ha si fún ènìyàn lórí ilẹ̀? 2Bí ọmọ ọ̀dọ̀ tí máa ń kánjú bojú wo òjìji, 3Bẹ́ẹ̀ ni a mú mi ní ìbànújẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù, 4Nígbà ti mo dùbúlẹ̀, èmi wí pé, ‘Nígbà wo ni èmi ó dìde?’ 5Kòkòrò àti ògúlùtu erùpẹ̀ ni á fi wọ̀ mi ni aṣọ, 6“Ọjọ́ mi yára jù ọkọ̀ ìhunṣọ lọ, 7Háà! Rántí pé afẹ́fẹ́ ni ẹ̀mí mi; 8Ojú ẹni tí ó rí mi, kì yóò rí mi mọ́; 9Bí ìkùùkuu tí i túká, tí í sì fò lọ, 10Kì yóò padà sínú ilé rẹ̀ mọ́, 11“Nítorí náà èmi kì yóò pa ẹnu mi mọ́, 12Èmi a máa ṣe Òkun tàbí ẹ̀mí búburú, 13Nígbà tí mo wí pé, ibùsùn mi yóò tù mí lára, 14Nígbà náà ni ìwọ fi àlá da yọ mi lénu bò mi, 15Bẹ́ẹ̀ ni ọkàn mí yàn láti fún pa 16O sú mi, èmi kò le wà títí: 17“Kí ni ènìyàn tí ìwọ o máa kókìkí rẹ̀? 18Àti ti ìwọ ó fi máa wá í bẹ̀ ẹ́ wò ni òròòwúrọ̀, 19Yóò ti pẹ́ tó kí ìwọ kí ó tó fi mí sílẹ̀ lọ, 20Èmi ti ṣẹ̀, ki ní èmi ó ṣe sí ọ. 21Èéṣe tí ìwọ kò sì dárí ìrékọjá mi jìn,

Limită Zilnică Atinsă

Upgrade-ază-ți planul pentru a continua să utilizezi funcțiile IA cu limite zilnice mai mari.

Compară toate planurile →