Hosea 13
1Nígbà ti Efraimu bá ń sọ̀rọ̀, àwọn ènìyàn máa ń wárìrì, 2Báyìí, wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀; 3Nítorí náà wọn yóò dàbí ìkùùkuu òwúrọ̀, 4“Ṣùgbọ́n Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ̀, 5Mo ṣe ìtọ́jú rẹ ní aginjù, 6Wọn ni ìtẹ́lọ́rùn nígbà tí mo fún wọn ní oúnjẹ, 7Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún, 8Beari igbó tí a já ọmọ rẹ̀ gbà, 9“A ti pa ọ́ run, ìwọ Israẹli, 10Níbo ni ọba rẹ gbé wà nísinsin yìí kí ó bá à le gbà ọ là? 11Nítorí èyí nínú ìbínú mi ni mo fún un yín ní ọba, 12Ẹ̀bi Efraimu ni a tí ko jọ 13Ìrora bí obìnrin tó fẹ́ bímọ ti dé bá a, 14“Èmi yóò rà wọ́n padà kúrò lọ́wọ́ agbára isà òkú. 15Bí ó tilẹ̀ gbilẹ̀ láàrín àwọn arákùnrin rẹ̀ Olúwa yóò wá, 16Ará Samaria gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn,