YOR Hioba Rozdział 31

Hioba 31

YOR · Porównaj · Audio

1Mo ti bá ojú mi dá májẹ̀mú, 2Nítorí pé kí ni ìpín Ọlọ́run láti ọ̀run wá? 3Kò ṣe pé àwọn ènìyàn búburú ni ìparun wà fún, 4Òun kò ha ri ipa ọ̀nà mi, 5“Bí ó bá ṣe pé èmi bá fi àìṣòótọ́ rìn, 6(jẹ́ kí Ọlọ́run wọ́n mí nínú ìwọ̀n òdodo, 7Bí ẹsẹ̀ mí bá yà kúrò lójú ọ̀nà, 8ǹjẹ́ kí èmi kí ó gbìn kí ẹlòmíràn kí ó sì mújẹ, 9“Bí àyà mi bá di fífà sí ipasẹ̀ obìnrin kan, 10kí àyà mi kí ó lọ ọlọ fún ẹlòmíràn, 11Nítorí pé yóò jẹ́ ohun ìtìjú àní, 12Nítorí pé iná ní èyí tí ó jó dé ibi ìparun, 13“Tí mo bá sì ṣe àìka ọ̀ràn ìránṣẹ́kùnrin mi 14kí ni èmi ó ha ṣe nígbà tí Ọlọ́run bá dìde? 15Ẹni tí ó dá mi ní inú kọ́ ni ó dá a? 16“Bí mo bá fa ọwọ́ sẹ́yìn fún ìfẹ́ inú tálákà, 17tàbí tí mo bá nìkan bu òkèlè mi jẹ, 18nítorí pé láti ìgbà èwe mi wá ni a ti tọ́ ọ dàgbà pẹ̀lú mi bí ẹni pé baba, 19bí èmi bá rí olùpọ́njú láìní aṣọ, 20bí ọkàn rẹ̀ kò bá súre fún mi, 21bí mo bá sì gbé ọwọ́ mi sókè sí aláìní baba, 22ǹjẹ́, ní apá mi kí o wọ́n kúrò ní ihò èjìká rẹ̀, 23Nítorí pé ìparun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá ni ẹ̀rù ńlá fún mi, 24“Bí ó bá ṣe pé mo fi wúrà ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé mi, 25bí mo bá yọ̀ nítorí ọrọ̀ mí pọ̀, 26bí mo bá bojú wo oòrùn nígbà tí ń ràn, 27bí a bá tàn ọkàn mi jẹ 28èyí pẹ̀lú ni ẹ̀ṣẹ̀ ti àwọn onídàájọ́ ní láti bẹ̀wò, 29“Bí ó bá ṣe pé mo yọ̀ sì ìparun ẹni tí ó kórìíra mi. 30Bẹ́ẹ̀ èmi kò sì jẹ ki ẹnu mi ki ó ṣẹ̀ 31Bí àwọn ènìyàn inú àgọ́ mi kò bá lè wí pé, 32Àlejò kò wọ̀ ni ìgboro rí; 33Bí mo bá bò ẹ̀ṣẹ̀ mi mọ́lẹ̀ bí Adamu ni pápá, 34Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni mo ha bẹ̀rù bí? 35(“Ìbá ṣe pé ẹnìkan le gbọ́ ti èmí! 36Nítòótọ́ èmí ìbá gbé le èjìká mi, 37Èmi ìbá sì sọ iye ìṣísẹ̀ mi fún un, 38“Bí ilẹ̀ mi bá sì ké rara lòdì sí mi 39Bí mo bá jẹ èso oko mi láìsan owó 40kí ẹ̀gún òṣùṣú kí ó hù dípò alikama,

Osiągnięto dzienny limit

Zmień plan na nowszy, aby kontynuować korzystanie z funkcji AI z wyższymi dziennymi limitami.

Porównaj wszystkie plany →