Sofoniasza 2
1Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, àní ẹ kó ra yín jọ pọ̀ 2kí a tó pa àṣẹ náà, kí ọjọ́ náà tó kọjá bí ìyàngbò ọkà, Olúwa tó dé bá a yín, Olúwa kí ó tó dé bá a yín. 3Ẹ wá Olúwa, gbogbo ẹ̀yin onírẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ náà, Olúwa. 4Nítorí pé, a ó kọ Gasa sílẹ̀, 5Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ń gbé etí Òkun, Olúwa dojúkọ ọ́, ìwọ Kenaani, 6Ilẹ̀ náà ní etí Òkun, ni ibùgbé àwọn ará Kereti, 7Agbègbè náà yóò sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ilé Juda, Olúwa Ọlọ́run wọn yóò bẹ̀ wọn wò, 8“Èmi ti gbọ́ ẹ̀gàn Moabu, 9Nítorí náà, bí Èmi tí wà,” Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 10Èyí ni ohun tí wọn yóò gbà padà nítorí ìgbéraga wọn, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ṣe ẹlẹ́yà. 11Olúwa yóò jẹ́ ìbẹ̀rù fún wọn; 12“Ẹ̀yin Etiopia pẹ̀lú, 13Òun yóò sì na ọwọ́ rẹ̀ sí apá àríwá, 14Agbo ẹran yóò sì dùbúlẹ̀ ni àárín rẹ̀, 15Èyí ni ìlú aláyọ̀ tí ó ń gbé láìléwu.