YOR Job Kapittel 32

Job 32

YOR · Sammenlign · Lyd

1Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí dákẹ́ láti dá Jobu lóhùn, nítorí ó ṣe olódodo lójú ara rẹ̀. 2Nígbà náà ni inú bí Elihu ọmọ Barakeli ará Busi, láti ìbátan ìdílé Ramu; ó bínú si Jobu nítorí ti ó dá ara rẹ̀ láre kàkà ki ó dá Ọlọ́run láre. 3Inú sì bí i sí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, nítorí tí wọn kò rí ọ̀nà láti dá Jobu lóhùn bẹ́ẹ̀ ni wọ́n dá Jobu lẹ́bi. 4Ǹjẹ́ Elihu ti dúró títí tí Jobu fi sọ̀rọ̀ tán nítorí tí àwọn wọ̀nyí dàgbà ju òun lọ ní ọjọ́ orí. 5Nígbà tí Elihu rí i pé ìdáhùn ọ̀rọ̀ kò sí ní ẹnu àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí nígbà náà ni ó bínú. 6Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, dáhùn ó sì wí pé, 7Èmi wí pé ọjọ́ orí ni ìbá sọ̀rọ̀, 8Ṣùgbọ́n ẹ̀mí kan ní ó wà nínú ènìyàn 9Ènìyàn ńlá ńlá kì í ṣe ọlọ́gbọ́n, 10“Nítorí náà ní èmí ṣe wí pé, ẹ dẹtí sílẹ̀ sí mi; 11Kíyèsi i, èmí ti dúró de ọ̀rọ̀ yín; 12àní, mo fiyèsí yín tinútinú. 13Kí ẹ̀yin kí ó má ṣe wí pé, ‘Àwa wá ọgbọ́n ní àwárí; 14Bí òun kò ti sọ̀rọ̀ sí mi, 15“Ẹnu sì yà wọ́n, wọn kò sì dáhùn mọ́, 16Mo sì retí, nítorí wọn kò sì fọhùn, wọ́n dákẹ́ jẹ́ẹ́; 17Bẹ́ẹ̀ ni èmí ó sì dáhùn nípa ti èmi, 18Nítorí pé èmi kún fún ọ̀rọ̀ sísọ, 19Kíyèsi i, ikùn mi dàbí ọtí wáìnì, tí kò ní ojú-ìhò; 20Èmí ó sọ, kí ara kí ó le rọ̀ mí, 21Lóòtítọ́ èmi kì yóò ṣe ojúsàájú sí ẹnìkankan, 22Nítorí pé èmí kò mọ̀ ọ̀rọ̀ ìpọ́nni í sọ ní ṣíṣe bẹ́ẹ̀,

Daglig grense nådd

Oppgrader planen din for å fortsette å bruke AI-funksjoner med høyere daglige grenser.

Sammenlign alle planer →