YOR Job Pasal 39

Job 39

YOR · Bandingkan · Audio

1Ìwọ mọ àkókò ìgbà tí àwọn ewúrẹ́ orí àpáta ń bímọ? 2Ìwọ lè ka iye òṣùpá tí wọn ń pé, 3Wọ́n tẹ ara wọn ba, wọ́n bímọ, 4Àwọn ọmọ wọn rí dáradára, wọ́n dàgbà nínú ọ̀dàn; 5“Ta ni ó jọ̀wọ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ oko lọ́wọ́? 6èyí tí mo fi aginjù ṣe ilé fún, 7Ó rẹ́rìn-ín sí ariwo ìlú, 8Orí àtòlé òkè ńlá ni ibùjẹ oko rẹ̀, 9“Àgbáǹréré ha jẹ́ sìn ọ́ bí? 10Ìwọ le fi òkun tata de àgbáǹréré nínú aporo? 11Ìwọ ó gbẹ́kẹ̀lé e nítorí agbára rẹ̀ pọ̀? 12Ìwọ le gbẹ́kẹ̀lé pé, yóò mú èso oko rẹ̀ wá sílé, 13“Ìwọ ni yóò ha fi ìyẹ́ dáradára fún ọ̀kín bí, 14Ó yé ẹ̀yìn rẹ̀ sílẹ̀ lórí ilẹ̀, 15tí ó sì gbàgbé pé, ẹsẹ̀ lè tẹ̀ wọ́n fọ́, 16Kò ní àánú sí àwọn ọmọ rẹ̀ bí ẹni pé wọn kì í ṣe tirẹ̀; 17nítorí pé Ọlọ́run kò fún un ní ọgbọ́n, 18Nígbà tí ó gbé ara sókè, 19“Ìwọ ni ó fi agbára fún ẹṣin bí, 20Ìwọ le mú fò sókè bí ẹlẹ́ǹgà? 21Ó fi ẹsẹ̀ halẹ̀ nínú àfonífojì, ó sì yọ̀ nínú agbára rẹ̀; 22Ó fi ojú kékeré wo ẹ̀rù, àyà kò sì fò ó; 23Lọ́dọ̀ rẹ ni apó-ọfà ń mì pẹkẹpẹkẹ, 24Ó fi kíkorò ojú àti ìbínú ńlá gbé ilé mi, 25Ó wí nígbà ìpè pé, Háà! Háà! 26“Àwòdì ha máa ti ipa ọgbọ́n rẹ̀ fò sókè, 27Idì ha máa fi àṣẹ rẹ̀ fò sókè, 28Ó ń gbé, ó sì ń wò ní orí àpáta, 29Láti ibẹ̀ lọ ni ó ti ń wá oúnjẹ kiri, 30Àwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú a máa mu ẹ̀jẹ̀,

Had Harian Dicapai

Tingkatkan pelan anda untuk terus menggunakan ciri AI dengan had harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua pelan →