YOR Job Pasal 10

Job 10

YOR · Bandingkan · Audio

1Agara ìwà ayé mi dá mi tán; 2Èmi yóò wí fún Ọlọ́run pé, má ṣe dá mi lẹ́bi; 3Ó ha tọ́ tí ìwọ ìbá fi máa ni mí lára, 4Ojú rẹ kì ha ṣe ojú ènìyàn bí? 5Ọjọ́ rẹ ha dàbí ọjọ́ ènìyàn, 6tí ìwọ fi ń béèrè àìṣedéédéé mi, 7Ìwọ mọ̀ pé èmi kì í ṣe oníwà búburú, 8“Ọwọ́ rẹ ni ó mọ mi, tí ó sì da mi. 9Èmi bẹ̀ ọ́ rántí pé ìwọ ti mọ mí bí amọ̀. 10Ìwọ kò ha ti tú mí dà jáde bí i wàrà, 11Ìwọ sá ti fi àwọ̀ ẹran-ara wọ̀ mí, 12Ìwọ ti fún mi ní ẹ̀mí àti ojúrere, 13“Nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ sì ti fi pamọ́ nínú rẹ; 14Bí mo bá ṣẹ̀, nígbà náà ni ìwọ yóò máa ṣọ́ mi 15Bí mo bá ṣe ẹni búburú, ègbé ni fún mi! 16Bí mo bá gbé orí mi ga, ìwọ ń dẹ mí kiri bi i kìnnìún 17Ìwọ sì tún mu àwọn ẹlẹ́rìí rẹ dìde sí mi di ọ̀tún 18“Nítorí kí ni ìwọ ṣe mú mi jáde láti inú wá? 19Tí kò bá le jẹ́ pé èmi wà láààyè, 20Ọjọ́ mi kò ha kúrú bí? Rárá! 21Kí èmi kí ó tó lọ sí ibi tí èmi kì yóò padà sẹ́yìn mọ́, 22ilẹ̀ òkùnkùn bí òkùnkùn tìkára rẹ̀,

Had Harian Dicapai

Tingkatkan pelan anda untuk terus menggunakan ciri AI dengan had harian yang lebih tinggi.

Bandingkan semua pelan →