YOR Cantico dei Cantici Capitolo 5

Cantico dei Cantici 5

YOR · Confronta · Audio

1Mo ti dé inú ọgbà mi, arábìnrin mi, ìyàwó mi; 2Mo ti sùn ṣùgbọ́n ọkàn mi jí. 3Mo ti bọ́ aṣọ ìgúnwà mi 4Olùfẹ́ mi na ọwọ́ rẹ̀ láti inú ihò ìlẹ̀kùn 5Èmi dìde láti ṣílẹ̀kùn fún olùfẹ́ mi, 6Èmi ṣí ìlẹ̀kùn fún olùfẹ́ mi, 7Àwọn olùṣọ́ tí ń ṣọ́ ìlú rí mi 8Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerusalẹmu, mo bẹ̀ yín 9Kí ni olùfẹ́ rẹ fi dára ju àwọn tókù lọ, 10Olùfẹ́ mi ní ìtànṣán ó sì pọ́n 11Orí rẹ̀ rí bí i wúrà tí ó dára jùlọ 12Ojú rẹ̀ rí bí i ti àdàbà 13Ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ rí bí ibùsùn tùràrí 14Apá rẹ̀ rí bí i ọ̀pá wúrà, 15Ẹsẹ̀ rẹ̀ rí bí i òpó mabu 16Ẹnu rẹ̀ jẹ́ adùn fún ara rẹ̀

Limite Giornaliero Raggiunto

Aggiorna il tuo piano per continuare a utilizzare le funzioni AI con limiti giornalieri più elevati.

Confronta tutti i piani →