Ayub 17
1“Ẹ̀mí mi bàjẹ́, 2Nítòótọ́ àwọn ẹlẹ́yà wà lọ́dọ̀ mi, 3“Fi fún mi Olúwa, ìlérí tí ìwọ fẹ́; 4Nítorí pé ìwọ ti sé wọ́n láyà kúrò nínú òye; 5Ẹni tí ó sọ ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn dídún fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ fún èrè, 6“Ọlọ́run ti sọ mi di ẹni òwe fún àwọn ènìyàn; 7Ojú mí ṣú bàìbàì nítorí ìbìnújẹ́, 8Àwọn olódodo yóò yanu sí èyí, 9Olódodo pẹ̀lú yóò di ọ̀nà rẹ̀ mú, 10“Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti gbogbo yín, 11Ọjọ́ tí èmi ti kọjá, ìrò mi ti fà yá, 12Àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń ṣọ́ òru di ọ̀sán; 13Bí mo tilẹ̀ ní ìrètí, ipò òku ní ilé mi; 14Èmi ti wí fún ìdíbàjẹ́ pé, ìwọ ni baba mi, 15ìrètí mi ha dà nísinsin yìí? 16Yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sínú ipò òkú,