Ayub 16
1Ìgbà náà ní Jobu dáhùn, ó sì wí pé, 2“Èmi ti gbọ́ irú ohun púpọ̀ bẹ́ẹ̀ rí 3Ọ̀rọ̀ asán lè ni òpin? 4Èmi pẹ̀lú le sọ bí ẹ̀yin; 5Èmi ìbá fi ọ̀rọ̀ ẹnu mi gbà yín ni ìyànjú, 6“Bí èmi tilẹ̀ sọ̀rọ̀, ìbìnújẹ́ mi kò lọ; 7Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ó dá mi lágara; 8Ìwọ fi ìhunjọ kùn mí lára, èyí tí o jẹ́rìí tì mí; 9Ọlọ́run fi i ìbínú rẹ̀ fà mí ya, ó sì gbóguntì mí; 10Wọ́n ti fi ẹnu wọn yẹ̀yẹ́ mi; 11Ọlọ́run ti fi mí lé ọwọ́ ẹni búburú, 12Mo ti jókòó jẹ́ẹ́, ṣùgbọ́n ó fà mí já; 13àwọn tafàtafà rẹ̀ dúró yí mi káàkiri. 14Ìbàjẹ́ lórí ìbàjẹ́ ní ó fi bà mí jẹ́; 15“Mo rán aṣọ ọ̀fọ̀ bò ara mi, 16Ojú mi ti pọ́n fún ẹkún, 17Kì í ṣe nítorí àìṣòótọ́ kan ní ọwọ́ mi; 18“Háà! Ilẹ̀ ayé, ìwọ má ṣe bò ẹ̀jẹ̀ mi, 19Ǹjẹ́ nísinsin yìí kíyèsi i, ẹlẹ́rìí mi ń bẹ ní ọ̀run, 20Àwọn ọ̀rẹ́ mi ń fi mí ṣẹ̀sín, 21ìbá ṣe pé ẹnìkan le è máa ṣe alágbàwí fún ẹnìkejì lọ́dọ̀ Ọlọ́run, 22“Nítorí nígbà tí iye ọdún díẹ̀ rékọjá tán,