YOR Job Capítulo 26

Job 26

YOR · Comparar · Audio

1ùgbọ́n Jobu sì dáhùn wí pé, 2“Báwo ni ìwọ ń ṣe ìrànlọ́wọ́ ẹni tí kò ní ipá, 3Báwo ni ìwọ ń ṣe ìgbìmọ̀ fun ẹni tí kò ní ọgbọ́n, 4Ta ni ó ràn ọ́ lọ́wọ́ láti sọ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, 5“Àwọn aláìlágbára ti isà òkú wárìrì, 6Ìhòhò ni ipò òkú níwájú Ọlọ́run, 7Òun ní o nà ìhà àríwá ọ̀run ní ibi òfúrufú, 8Ó di omi pọ̀ nínú ìkùùkuu àwọsánmọ̀ rẹ̀ tí ó nípọn; 9Ó sì fa ojú ìtẹ́ rẹ̀ sẹ́yìn, 10Ó fi ìdè yí omi òkun ká, 11Ọ̀wọ́n òpó ọ̀run wárìrì, 12Ó fi ipá rẹ̀ dààmú omi Òkun; 13Nípa ẹ̀mí rẹ̀ ni ó ti ṣe ọ̀run ní ọ̀ṣọ́; 14Kíyèsi i, èyí ní òpin ọ̀nà rẹ̀;

Límite diario alcanzado

Actualiza tu plan para continuar usando funciones de IA con límites diarios más altos.

Comparar todos los planes →