YOR Isaías Capítulo 55

Isaías 55

YOR · Comparar · Audio

1Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òǹgbẹ ń gbẹ, 2Èéṣe tí ẹ fi ń ná owó fún èyí tí kì í ṣe àkàrà 3Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi; 4Kíyèsi i, mo ti fi òun ṣe ẹlẹ́rìí fún àwọn ènìyàn, 5Lóòtítọ́ ìwọ yóò ké sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò mọ̀ Olúwa Ọlọ́run rẹ 6Ẹ wá Olúwa nígbà tí ẹ lè rí i; 7Jẹ́ kí ìkà kí ó kọ ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀ Olúwa, Òun yóò sì ṣàánú fún un, 8“Nítorí èrò mi kì í ṣe èrò yín, Olúwa wí. 9“Gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti ga ju ayé lọ, 10Gẹ́gẹ́ bí òjò àti yìnyín 11bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tí ó jáde láti ẹnu mi wá; 12Ẹ̀yin yóò jáde lọ ní ayọ̀ 13Dípò igi ẹ̀gún ni igi junifa yóò máa dàgbà, Olúwa,

Límite diario alcanzado

Actualiza tu plan para continuar usando funciones de IA con límites diarios más altos.

Comparar todos los planes →