Ιώβ 4
1Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani dáhùn wí pé, 2“Bí àwa bá fi ẹnu lé e, láti bá ọ sọ̀rọ̀, ìwọ o ha banújẹ́? 3Kíyèsi i, ìwọ sá ti kọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn, 4Ọ̀rọ̀ rẹ ti gbé àwọn tí ń ṣubú lọ dúró, 5Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ó dé bá ọ, ó sì rẹ̀ ọ́, ó kọlù ọ́; 6Ìbẹ̀rù Ọlọ́run rẹ kò ha jẹ́ ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ 7“Èmi bẹ̀ ọ́ rántí, ta ni ó ṣègbé rí láìṣẹ̀? 8Àní bí èmi ti rí i pé, àwọn tí ń ṣe ìtulẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀, 9Nípa ìfẹ́ sí Ọlọ́run wọn a ṣègbé, 10Bíbú ramúramù kìnnìún àti ohùn òǹrorò kìnnìún 11Kìnnìún kígbe, nítorí àìrí ohun ọdẹ, 12“Ǹjẹ́ nísinsin yìí a fi ohun àṣírí kan hàn fún mi, 13Ní ìrò inú lójú ìran òru, 14Ẹ̀rù bà mí àti ìwárìrì 15Nígbà náà ni ẹ̀mí kan kọjá lọ ní iwájú mi, 16Ó dúró jẹ́ẹ́, 17‘Ẹni kíkú le jẹ́ olódodo ju Ọlọ́run, 18Kíyèsi i, òun kò gbẹ́kẹ̀lé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, 19Mélòó mélòó àwọn tí ń gbé inú ilé amọ̀, 20A pa wọ́n run láàrín òwúrọ̀ àti àṣálẹ́ 21A kò ha ké okùn iye wọ́n kúrò bí?