YOR Ιώβ Κεφάλαιο 14

Ιώβ 14

1Ènìyàn tí a bí nínú obìnrin, 2Ó jáde wá bí ìtànná ewéko, a sì ké e lulẹ̀; 3Ìwọ sì ń síjú rẹ wò irú èyí ni? 4Ta ni ó lè mú ohun mímọ́ láti inú àìmọ́ jáde wá? 5Ǹjẹ́ a ti pinnu ọjọ́ rẹ̀, 6Yípadà kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, kí ó lè sinmi, 7“Nítorí pé ìrètí wà fún igi, bí a bá 8Bí gbòǹgbò rẹ̀ tilẹ̀ di ogbó nínú ilẹ̀, 9síbẹ̀ nígbà tí ó bá gbóòórùn omi, 10Ṣùgbọ́n ènìyàn kú, a sì dàánù, 11“Bí omi ti í tán nínú ipa odò, 12bẹ́ẹ̀ ni ènìyàn dùbúlẹ̀ tí kò sì dìde mọ́; 13“Háà! ìwọ ìbá fi mí pamọ́ ní ipò òkú, 14Bí ènìyàn bá kú yóò sì tún yè bí? 15Ìwọ ìbá pè, èmi ìbá sì dá ọ lóhùn; 16Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ìwọ ń kaye ìṣísẹ̀ mi; 17A fi èdìdì di ìrékọjá mi sínú àpò, 18“Àti nítòótọ́ òkè ńlá tí ó ṣubú, ó dasán, 19Omi a máa yinrin òkúta, ìwọ a sì 20Ìwọ ṣẹ́gun rẹ̀ láéláé, òun sì kọjá lọ! 21Àwọn ọmọ rẹ̀ bọ́ sí ipò ọlá, òun kò sì mọ̀; 22Ṣùgbọ́n ẹran-ara rẹ̀ ni yóò rí ìrora

Ημερήσιο Όριο Φτάσιμο

Αναβαθμίστε το πακέτο σας για να συνεχίσετε να χρησιμοποιείτε τις λειτουργίες ΑΙ με υψηλότερα ημερήσια όρια.

Σύγκριση όλων των προγραμμάτων →