YOR Hiob Kapitel 3

Hiob 3

YOR · Vergleichen · Audio

1̀yìn èyí ní Jobu yanu, ó sì fi ọjọ́ ìbí rẹ̀ ré 2Jobu sọ, ó sì wí pé, 3“Kí ọjọ́ tí a bí mi kí ó di ìgbàgbé, 4Kí ọjọ́ náà kí ó já si òkùnkùn, 5Kí òkùnkùn àti òjìji ikú fi ṣe ti ara wọn; 6Kí òkùnkùn kí ó ṣú bo òru náà biribiri, 7Kí òru náà kí ó yàgàn; 8Kí àwọn tí í fi ọjọ́ gégùn ún kí o fi gégùn ún, 9Kí ìràwọ̀ òwúrọ̀ ọjọ́ rẹ̀ kí ó ṣókùnkùn; 10nítorí tí kò sé ìlẹ̀kùn inú ìyá mi, 11“Èéṣe tí èmi kò fi kú láti inú wá, 12Èéṣe tí orúnkún wá pàdé mi, 13Ǹjẹ́ nísinsin yìí èmi ìbá ti dùbúlẹ̀ jẹ́ẹ́; 14pẹ̀lú àwọn ọba àti ìgbìmọ̀ ayé 15Tàbí pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládé 16Tàbí bí ọlẹ̀ tí a sin, èmi kì bá ti sí: 17Níbẹ̀ ni ẹni búburú ṣíwọ́ ìyọnilẹ́nu, 18Níbẹ̀ ni àwọn ìgbèkùn sinmi pọ̀, 19Àti èwe àti àgbà wà níbẹ̀, 20“Nítorí kí ni a ṣe fi ìmọ́lẹ̀ fún òtòṣì, 21tí wọ́n dúró de ikú, ṣùgbọ́n òun kò wá, 22Ẹni tí ó yọ̀ gidigidi, 23Kí ni a fi ìmọ́lẹ̀ fún ẹni 24Nítorí pé èémí-ẹ̀dùn wà ṣáájú oúnjẹ mi; 25Nítorí pé ohun náà tí mo bẹ̀rù gidigidi ni ó dé bá mi yìí, 26Èmi wà láìní àlàáfíà, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ní ìsinmi;

Tägliches Limit erreicht

Aktualisieren Sie Ihren Plan, um KI-Funktionen mit höheren täglichen Limits weiter nutzen zu können.

Alle Tarife vergleichen →