Micah 2
1Ègbé ni fún àwọn tí ń gbèrò àìṣedéédéé 2Wọ́n sì ń ṣe ojúkòkòrò oko, wọ́n sì fi agbára wọn gbà wọ́n, 3Nítorí náà, Olúwa wí pé: 4Ní ọjọ́ náà ni ẹnìkan yóò pa òwe kan sí yín; Olúwa ti pín ohun ìní àwọn ènìyàn mi; 5Nítorí náà, ìwọ kò ní ní ẹnìkankan tí yóò ta okùn nínú ìjọ Olúwa, 6“Ẹ má ṣe sọtẹ́lẹ̀,” ni àwọn wòlíì wọn wí. 7Ṣé kí á sọ ọ́, ìwọ ilé Jakọbu: Olúwa ha ń bínú bí? 8Láìpẹ́ àwọn ènìyàn mi dìde 9Ẹ̀yin sì lé obìnrin àwọn ènìyàn mi 10Ẹ dìde, kí ẹ sì máa lọ! 11Tí òpùrọ́ àti ẹlẹ́tàn bá wà tí wọ́n sì wí pé, 12“Èmi yóò kó gbogbo yín jọ, ìwọ Jakọbu; 13Ẹni tí ó ń fọ ọ̀nà yóò lọ sókè níwájú wọn; Olúwa ni yóò sì ṣe olórí wọn.”