YOR Job Kapitola 38

Job 38

YOR · Porovnat · Audio

1Nígbà náà ní Olúwa dá Jobu lóhùn láti inú ìjì àjàyíká wá, ó sì wí pé, 2“Ta ni èyí tí ń fi ọ̀rọ̀ àìlóye 3Di ẹ̀gbẹ́ ara rẹ ní àmùrè bí ọkùnrin nísinsin yìí, 4“Níbo ni ìwọ wà nígbà tí mo fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀? 5Ta ni ó fi ìwọ̀n rẹ lélẹ̀, dájú bí ìwọ bá mọ̀ ọ́n? 6Lórí ibo ni a gbé kan ìpìlẹ̀ rẹ̀ mọ́, 7nígbà náà àwọn ìràwọ̀ òwúrọ̀ jùmọ̀ kọrin pọ̀, 8“Tàbí ta ni ó fi ìlẹ̀kùn sé omi òkun mọ́, 9Nígbà tí mo fi àwọsánmọ̀ ṣe aṣọ rẹ̀, 10Nígbà tí mo ti pàṣẹ ìpinnu mi fún un, 11Tí mo sì wí pé níhìn-ín ni ìwọ ó dé, kí o má sì rékọjá, 12“Ìwọ pàṣẹ fún òwúrọ̀ láti ìgbà ọjọ́ rẹ̀ wá, 13í ó lè di òpin ilẹ̀ ayé mú, 14Kí ó yí padà bí amọ̀ fún èdìdì amọ̀, 15A sì fa ìmọ́lẹ̀ wọn sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ ènìyàn búburú, 16“Ìwọ ha wọ inú ìsun òkun lọ rí bí? 17A ha ṣílẹ̀kùn ikú sílẹ̀ fún ọ rí bí, 18Ìwọ mòye ìbú ayé bí? 19“Ọ̀nà wo ni ìmọ́lẹ̀ ń gbé? 20tí ìwọ í fi mú un lọ sí ibi àlá rẹ̀, 21Ìwọ mọ èyí, nítorí nígbà náà ni a bí ọ? 22“Ìwọ ha wọ inú ìṣúra ìdì òjò lọ rí bí, 23tí mo ti fi pamọ́ de ìgbà ìyọnu, 24Ọ̀nà wo ni ó lọ sí ibi tí ìmọ́lẹ̀ fi ń la, 25Ta ni ó la ipadò fún ẹ̀kún omi, 26láti mú u rọ̀jò sórí ayé níbi tí ènìyàn kò sí, 27láti mú ilẹ̀ tútù, ijù àti aláìro 28Òjò ha ní baba bí? 29Láti inú ta ni ìdì omi ti jáde wá? 30Nígbà tí omi di líle bí òkúta, 31“Ìwọ ha le fi ọ̀já de àwọn ìràwọ̀ Pleiadesi dáradára? 32Ìwọ le mú àwọn àmì méjìlá ìràwọ̀ Masaroti jáde wá nígbà àkókò wọn? 33Ǹjẹ́ ìwọ mọ ìlànà ọ̀run? 34“Ìwọ le gbé ohùn rẹ sókè dé àwọsánmọ̀ 35Ìwọ le rán mọ̀nàmọ́ná kí wọn kí ó le lọ, 36Ta ni ó fi ọgbọ́n pamọ́ sí odò ikùn 37Ta ni ó fi ọgbọ́n ka iye àwọsánmọ̀? 38nígbà tí erùpẹ̀ di líle, 39“Ìwọ ha dẹ ọdẹ fún abo kìnnìún bí? 40nígbà tí wọ́n bá mọ́lẹ̀ nínú ihò 41Ta ni ó ń pèsè ohun jíjẹ fún ẹyẹ ìwò,

Dosažen denní limit

Upgraďte svůj plán a pokračujte v používání funkcí AI s vyššími denními limity.

Porovnat všechny plány →